YouVersion logo
BijbelLeesplannenVideo's
Download de app
Taalkiezer
Zoek icoon

Populaire Bijbelverzen uit ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27

1

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:25

Yoruba Bible

YCE

Nítorí náà ẹ̀yin eniyan, ẹ ṣara gírí, nítorí mo gba Ọlọrun gbọ́ pé bí ó ti sọ fún mi ni yóo rí.

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:25

2

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:23-24

Yoruba Bible

YCE

Nítorí ní alẹ́ àná, angẹli Ọlọrun mi, tí mò ń sìn dúró tì mí, ó ní, ‘Má bẹ̀rù, Paulu. Dandan ni kí o dé iwájú Kesari. Mo fẹ́ kí o mọ̀ pé Ọlọrun ti fi ẹ̀mí gbogbo àwọn ẹni tí ó wọkọ̀ pẹlu rẹ jíǹkí rẹ.’

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:23-24

3

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22

Yoruba Bible

YCE

Ṣugbọn bí ó ti rí yìí náà, mo gbà yín níyànjú pé kí ẹ ṣara gírí. Ẹ̀mí ẹnikẹ́ni ninu yín kò ní ṣòfò; ọkọ̀ nìkan ni yóo ṣòfò.

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:22

Gratis leesplannen en overdenkingen die te maken hebben met ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27

Vorig hoofdstuk
Volgend hoofdstuk
YouVersion

Moedigt jou aan en daagt je uit om elke dag gemeenschap met God te zoeken.

Bediening

Over

Carrières

Vrijwilliger

Blog

Pers

Nuttige links

Help

Bijdragen

Bijbelvertalingen

Luisterbijbels

Bijbeltalen

Tekst van de Dag


Een digitale bediening van

Life.Church
Nederlands (Nederland)

©2026 Life.Church / YouVersion

PrivacybeleidVoorwaarden
Programma voor openbaarmaking van kwetsbaarheden
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest