YouVersion logo
BijbelLeesplannenVideo's
Download de app
Taalkiezer
Zoek icoon

Populaire Bijbelverzen uit ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28

1

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:31

Yoruba Bible

YCE

Ó ń waasu ìjọba Ọlọrun. Ó ń kọ́ àwọn eniyan nípa Oluwa Jesu Kristi láì bẹ̀rù ohunkohun. Ẹnikẹ́ni kò sì dí i lọ́wọ́.

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:31

2

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:5

Yoruba Bible

YCE

Paulu kàn gbọn ejò náà sinu iná ni, ohun burúkú kan kò sì ṣẹlẹ̀ sí i.

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:5

3

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:26-27

Yoruba Bible

YCE

Ó ní, ‘Lọ sọ fún àwọn eniyan yìí pé: Ẹ óo fetí yín gbọ́, ṣugbọn kò ní ye yín; Ẹ óo wò ó títí, ṣugbọn ẹ kò ní mọ̀ ọ́n. Nítorí ọkàn àwọn eniyan yìí kò ṣí; wọ́n ti di alágbọ̀ọ́ya, wọ́n ti dijú. Bí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, wọn ìbá fi ojú wọn ríran, wọn ìbá fetí gbọ́ràn, òye ìbá yé wọn, wọn ìbá yipada; èmi ìbá sì wò wọ́n sàn.’

Vergelijk

Ontdek ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:26-27

Vorig hoofdstuk
Volgend hoofdstuk
YouVersion

Moedigt jou aan en daagt je uit om elke dag gemeenschap met God te zoeken.

Bediening

Over

Carrières

Vrijwilliger

Blog

Pers

Nuttige links

Help

Bijdragen

Bijbelvertalingen

Luisterbijbels

Bijbeltalen

Tekst van de Dag


Een digitale bediening van

Life.Church
Nederlands (Nederland)

©2026 Life.Church / YouVersion

PrivacybeleidVoorwaarden
Programma voor openbaarmaking van kwetsbaarheden
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest