Ìtàn Nípa Ọgbọn ỌlọrunÀpẹrẹ

Agbara Ogbon
Awọn Oba kólé Jọba Laisi Ọgbọn bẹ nà awọn to òun dari orilẹ ède Lai sìi, Ọgbọn jẹ àgbàrá to ṣe kókó nínú ṣiṣe oludari. Oludari ti o bá ni, ò dájú yíò ni ijakulẹ̀.
Nipà bayí ,Ọgbọn jẹ àgbàrá , o jẹ àgbàrá lati ṣàkóso pẹlu aseyori ni ipele gbogbo; lori ilé iṣẹ́ ati idile, ṣiṣe àkóso lori ìdílé pẹlú Ọgbọn ko ṣe mú Kúrò.
Àwòrán Nla na niyi;Ọgbọn Ọlọrun fún wà láti ṣe aṣeyọri ni gbogbo ipo ti a ba àrà wá bi adari ni ayé ṣe pàtàkì, ìwúlò rẹ ṣe pàtàkì bi ìwúlò ēmi lati yé.
Oba Solomoni ni ìwé Oniwasu so wípé; " Ọgbọn jẹ ohun igbeja, o ṣi jẹ Iye fún awọn to ni ¹, eleyii fi àgbàrá to wa nínú Ọgbọn hán ati ipá rẹ̀ lati gbèro ati lati daabobo awọn to ni. Njẹ, iwọ kí o ha ṣafẹri Ọgbọn yii.
Kika siwaju: Oniwasu 7:12, Owe 1:5, 2:10-12
Adura: OLUWA, Mò gba Òré ọfẹ lati ma lépa Ọgbọn rẹ ni ìgbà gbogbo.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL