Ohun Èlò Bíbélì jẹ ọfẹ pátápátá, laisi ìpolówó àti àwọn rírà ni-app. Gba ohun èlò
Akọọlẹ oníròyìn

Ọjọ́ 365
Ako ètò akọọlẹ oníròyìn òní lẹta buluu jọ gẹgẹ bíi ìwádìí ìtàn aipẹ, a to àwọn akọọlẹ náà gẹgẹ bí wọn ṣe ṣẹlẹ gangan. Èyí jẹ́ ètò tí o dára púpò láti tẹle tí o bá fẹ́ láti ṣàfikún ìtàn sí kíka Bíbélìi rẹ. Bí a bá tẹle ètò yìí bí a ṣe pèsè rẹ silẹ, gbogbo Bíbélì ni a o ka nínú ọdún kan.
À se ipèsè ètò kíkà yìí látọwọ́ Bíbélì oni lẹta buluu.
Àwọn Ètò tó Jẹmọ́ọ

Kika Ìtàn Ọlọhun: Eto Iṣiro Kan Odun kan

Fun Eto Ayọ Ṣaaju Rẹ: Ẹrọ Ọjọ ajinde Kristi

Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì nípa Ìdúpẹ́ Látọwọ́ Paul Tripp

Ìyìn: Àṣàrò nínú Orin Dáfídì

Bí A Ti Lè Bẹ̀rẹ̀ Sí Ní Ka Bíbélì

Ọkùnrin Orí Àgbélébùú Àárín: Ètò Bíbélì Ọlọ́jọ́ Méje Tí Àjínde

Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú Olúwa

Ka Májẹ̀mú Titun Já

Elíshà: Ìtàn Ìgbàgbọ́ Tí ó pe ni Níjà
