Ọjọ́ Falentáìnì

Ọjọ́ 3
Ọjọ́ Falentáìnì lè jẹ́ àkókò ẹ̀tàn fún díẹ̀ nínú wa. A lè wà ní ìpele kan tí a kò sí nínú ìdá ọ̀rẹ́ pẹ̀lú ẹnì kankan, ṣùgbọ́n tí ó wù wá pé kí á ní ọ̀rẹ́, èyí tí ó lè má rọrùn fún wa. Ní ọjọ́ mẹ́ta tí ó ńbọ̀ yìí, láì bìkítà ipò ìbátan rẹ, jẹ́ kí á gba ọkàn rẹ ní ìyànjú pẹ̀lú ìfẹ́ Ọlọ́run ALÁRINRIN, ALÁÌNÍ ÌTORÍ, ÌDÁKẸ́JẸ́.
A fẹ́ dúpẹ́ l'ọwọ́ CBN Europe fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé sí iwájú síi, ṣe àbẹ̀wò: https://www.cbneurope.com/yv