Títẹ̀lé Jésù Olùgbèjà WaÀpẹrẹ

Jésù Àti Ìjìyà Náà.
Ìjìyà, bìí òṣì, lè pín sí oríṣiríṣi ọ̀nà. Jésù ṣe àkíyèsí àwọn tí ó ń jìyà ní ara tàbí ní Ẹ̀mí ó sì dáhùn ẹ̀bẹ̀ wọ́n.
Láti inú Ẹ̀kọ́ Bíbélì tí Afrika àwọn òwe àti ìtàn àkọsílẹ̀ tí àkòrí rẹ jẹ "Fọ́jú Tó bẹ̀ẹ́ láti Rírán":
Ọ̀rọ̀ tí ó gbajúgbajà tí a máà ń sọ gẹ́gẹ́ bí àṣà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè Afrika, pàápàá ní àárín Mendi ní ilẹ̀ Saro pé "ọmọ tí ó bá kígbe sókè ju ní yíò pé ìyá rẹ sì àkíyèsí"
Afọ́jú alágbè ní ẹ̀bá ọ̀nà tí ó lọ sí Jẹ́ríkò kò lè sáré tọ Jésù, ṣùgbọ́n ó fí ohùn rẹ pè Jésù sí àkíyèsí. Ó pariwo-ó sì pé Jésù sì àkíyèsí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí ó bá kígbe sókè ṣe lè pé àwọn òbí rẹ̀ sì àkíyèsí
Kíkígbe pè Jésù pẹ̀lú ìgbàgbọ́, láì ká irú ipò tí ó wà sì, yíò pè sì àkíyèsí. Ibí yí ní ìdáhùn sí àdúrà rẹ tí bẹ̀rẹ̀ Ìwọ kò nílò láti jìyà ní ìpalọ́lọ́ tàbí kó dá ẹrù náà gbé; Jésù sún mọ́ ọ pẹ́típẹ́tí ó kàn ní láti ké pè orúkọ Rẹ̀ nínú àdúrà ní.
Àṣàrò tàbí Ìjíròrò
Nípa ìhùwàsí afọ́jú náà ó dàbí ẹni pé ó tí mọ ẹni tí Jésù í ṣe tẹ́lẹ̀. Kíni ohun náà tí ó tí lè gbọ́ nípa Jésù? What might he have heard about Jesus?
Àwọn èrò pé ní "Jésù tí Násárétì", ṣùgbọ́n afọ́jú ní pe ní "Jésù, ọmọ Dáfídì". Kíni àwọn orúkọ méjì tí ó yàtọ̀ yí sọ fún wa nípa Jésù?
Kí ló dé tí Jésù fí béèrè lọwọ afọ́jú ní ńkan tí ó ń fẹ́ nígbàtí Ó rí àrídájú rẹ
Ń jẹ ó ní ohun tí ó jẹ mọ́ ìyá nínú ayé rẹ tí ó tí nílò Jésù láti rán ọ lọ́wọ́ nísinsìnyí? Sọ fún nípa rẹ̀ nínú àdúrà.
Idagbasoke Bọtini ọjọ_5 ọjọ_5Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Oníbárà tó f'ọ́jú kan tó ń kígbe rara ní ẹ̀bá ọ̀nà, obìnrin kan tí ìgbé-ayé rẹ̀ kò tọ̀nà ní ojú mùtúmùwà tó mọ̀ọ́ṣe, òṣìṣẹ́ ìjọba kan tí gbogbo ènìyàn kórìíra – báwo ni ìkankan nínú àwọn ènìyàn yìí tí àwùjọ ti ta dànù ṣe lè ní ìrètí ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run mímọ́? Pẹ̀lú àwọn ìlanilọ́yẹ̀ látinú ìwé Lúùkù nínú Bíbélì Àṣàrò fún Afrika, a ó máa tẹ̀lé Jésù bí ó ti ńṣe ìparẹ́ àwọn àlà tó wà láàárín Ọlọ́run àti àwọn tí a ti gbá sí ẹ̀gbẹ́ láwùjọ.
More