Àṣàrò Nípa Kérésìmesì

Ọjọ́ 5
Ìtàn Kérésìmesì wa bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìkéde áńgẹ́lì sí Màríà ó sì parí pẹ̀lú ìbẹ̀wò àwọn amòye. Nínú àwọn àṣàrò wọ̀nyí àti àwọn àmúlò ti ìtàn àkọsílẹ̀ Kérésìmesì èmi yóò tọ́ka sí ìwé Lúùkú púpọ̀, nítorí ìwé tirẹ̀ ni ó kún jùlọ nínú àwọn àkọsílẹ̀ ìhìnrere.
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Simon McIntyre fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ kàn sí: https://www.simonmcintyre.net/