Ìtàn Ọjọ ÀjíndeÀpẹrẹ

The Story of Easter

Ọjọ́ 3 nínú 7

Ọjọ Ọjọ́rú

Jésu ni ìbéèrè ikẹhin. O mọ idòjukọ rẹ ni ọjọ keji, ṣugbọn adura kẹhin rẹ kii ṣe fun ara Rẹ, ṣugbọn fun ọ. Fun gbogbo wa. Jesu gbadura fun awọn ọmọ-ẹhin Rẹ. Adura Jesu jẹ fèrèsé iyanu sínú ifẹ Ọlọrun fun wa. Jẹ ìdáhùn si ádùrá Jésù ni ọsẹ yii. Ká ádùrá rẹ lẹsẹsẹ lati mọ bi ó sè gbà. Ni ipari ọsẹ yii, bi Ijọ àgbáyé yóò ti parapọ̀ lati ṣe ayẹyẹ ajinde rẹ, ẹjẹ ki a wa ọna lati jẹ ọkan pẹlu Ọlọrun ati ọkan pẹlu ará wa. Jẹki adura Jesu jẹ adura rẹ, kí gbogbo ayé lè ri ògo rẹ, ki wọn si mọ nipasẹ isokan wà ati ifẹ Ọlọrun.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

The Story of Easter

Bawo ni iwọ yoo ṣe lo ọsẹ ikẹhin ti igbesi aye rẹ ti osi mọ pe o jẹ opin rẹ? Ni ose to koja Jesu wà lori ilẹ ni irisi eniyan ti o kún fun awọn asiko to ṣe iranti, awọn asotele ti o ṣẹ, adura timọtimo, ijiroro jinna, awọn iṣẹ apẹẹrẹ, ati awọn iṣẹlẹ iyipada aye. Ti a ṣe lati bẹrẹ ni Ọjọ-aarọ ṣaaju Ọjọ ajinde, ọjọ kọọkan ti Aye Life.Church eto bibeli n rin ọ nipase itan isọtẹlẹ ti ọsẹ mimọ.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ Life.Church fun pese eto yii. Ti o ba fẹ lati ni imọ siwaju sii nipa Life.Church, jọwọ lọsi: www.Life.Church