Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 6 nínú 30

Melo ninu ìgbàgbọ́, ìrètí ati ifẹ́ ni on sise
ti aba gbìyànjú láti dá enìkan lójú? Kon kii se iṣẹ́ wa láti dá àwọn ẹlomiran lójú,, o je ásọtúnsọ ọ̀gbọ́n lásánlàsàn, kì í ṣe ìgbésí ayé tẹ̀mí. Émí Ọlọ́run mase idánilójú ti a ba wani ìbáṣepò nibi ti a wa wulẹ̀ fi òrò Ọlọ́run kọ́ni. A wa fi òrò Ọlọ́run sèfà jẹ ki a bàa lè wani ibamu si awon èrò ti awa gangan ti pèsè; àmọ́ nígba to ba kan íparôrô àlàáfíà ńlá ati isimi Olúwa Jésù, a le dán ibi ta wa wo nírọ̀rùn.
Làti “simi nínú Olúwa” oje iṣẹ́ pípé ti bẹ ní ìhà inú. Ni ọ́gbọ́n lásán ti èèyàn o tu mo si ki eni jókòó pẹ̀lú ọ̀wọ́ kiká ka jé kí Ọlọ́run ṣe gbogbo iṣẹ́; ni òdodo oje wíwà ni ididúró sinsin nínú Ọlọ́run toje wipe awa ni òmìnira lati ṣe iṣẹ́ ti èèyàn laisi awuyewuye. Igbà ti Ọlọ́run n sẹ iṣẹ́ àgbàyanu julo ni igbà ti a wa ko lero.

Ìbéèrè Ijiroro: Mèwo nínù àinisimi wa lowa làti igbìyànjú làti ṣẹ̀dá àlàáfíà lori ọ̀nà wa dípò ti Olórun? Èwo nínù apá àlàáfíà-dídá jẹ́ ti Olórun atipe èwo lojẹ́ tèmi?

Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a Mu Làti Bí Èyín Ba Wàá ni Pípé, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org