Ifi 3:2
Ifi 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Jí, kí o sì fi ẹsẹ̀ ohun tí ó kù múlẹ̀, tàbí tí ó ṣetán láti kú: Nítorí èmi kò rí iṣẹ́ rẹ ni pípé níwájú Ọlọ́run.
Pín
Kà Ifi 3Ifi 3:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Mã ṣọra, ki o si fi ẹsẹ ohun ti o kù mulẹ, ti o ṣe tan lati kú: nitori emi kò ri iṣẹ rẹ ni pipé niwaju Ọlọrun.
Pín
Kà Ifi 3Ifi 3:2 Yoruba Bible (YCE)
Jí lójú oorun! Fún àwọn ohun tí ó ṣẹ́kù ní okun, nítorí àwọn náà ń kú lọ. Nítorí n kò rí iṣẹ́ kan tí o ṣe parí níwájú Ọlọrun mi.
Pín
Kà Ifi 3Ifi 3:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Mã ṣọra, ki o si fi ẹsẹ ohun ti o kù mulẹ, ti o ṣe tan lati kú: nitori emi kò ri iṣẹ rẹ ni pipé niwaju Ọlọrun.
Pín
Kà Ifi 3