O. Daf 93:1
O. Daf 93:1 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA jọba; ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí ẹ̀wù; OLUWA gbé ọlá ńlá wọ̀, ó sì di agbára ni àmùrè. Ó fi ìdí ayé múlẹ̀; kò sì ní yẹ̀ laelae.
Pín
Kà O. Daf 93O. Daf 93:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA jọba, ọla-nla li o wọ li aṣọ; agbara ni Oluwa wọ̀ li aṣọ, o fi di ara rẹ̀ li amure: o si fi idi aiye mulẹ, ti kì yio fi le yi.
Pín
Kà O. Daf 93