Saamu 93:1

Saamu 93:1 YCB

OLúWA ń jẹ ọba, ọláńlá ni ó wọ̀ ní aṣọ; ọláńlá ni OLúWA wọ̀ ní aṣọ àti ìhámọ́ra rẹ̀ pẹ̀lú agbára. Ó fi ìdí ayé múlẹ̀; kò sì le è yí.