Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 77:1-2

O. Daf 77:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)

EMI fi ohùn mi kigbe si Ọlọrun, ani si Ọlọrun ni mo fi ohùn mi kepè; o si fi eti si mi. Li ọjọ ipọnju mi emi ṣe afẹri Ọlọrun: ọwọ mi nnà li oru, kò si rẹ̀ silẹ: ọkàn mi kọ̀ ati tù ninu.

Pín
Kà O. Daf 77

O. Daf 77:1-2 Yoruba Bible (YCE)

Mo ké pe Ọlọrun fún ìrànlọ́wọ́, mo kígbe pe Ọlọrun kí ó lè gbọ́ tèmi. Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA; ní òru, mo tẹ́wọ́ adura láìkáàárẹ̀, ṣugbọn n kò rí ìtùnú.

Pín
Kà O. Daf 77

O. Daf 77:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Mó kígbe sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́; mo kígbe sí Ọlọ́run láti gbọ́ tèmi. Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú, mo wá OLúWA; ní òru ni mo na ọwọ́ mi jáde ní àìkáárẹ̀ ọkàn mí sì kọ̀ láti tù ú nínú.

Pín
Kà O. Daf 77
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò