ORIN DAFIDI 77:1-2

ORIN DAFIDI 77:1-2 YCE

Mo ké pe Ọlọrun fún ìrànlọ́wọ́, mo kígbe pe Ọlọrun kí ó lè gbọ́ tèmi. Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA; ní òru, mo tẹ́wọ́ adura láìkáàárẹ̀, ṣugbọn n kò rí ìtùnú.