O. Daf 130:6
O. Daf 130:6 Yoruba Bible (YCE)
Mò ń retí rẹ, OLUWA, ju bí àwọn aṣọ́de ti máa ń retí kí ilẹ̀ mọ́ lọ, àní, ju bí àwọn aṣọ́de, ti máa ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.
O. Daf 130:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọkàn mi duro dè Oluwa, jù awọn ti nṣọ́na owurọ lọ, ani jù awọn ti nṣọ́na owurọ lọ.