ORIN DAFIDI 130:6

ORIN DAFIDI 130:6 YCE

Mò ń retí rẹ, OLUWA, ju bí àwọn aṣọ́de ti máa ń retí kí ilẹ̀ mọ́ lọ, àní, ju bí àwọn aṣọ́de, ti máa ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.