Oba 1:1 - Compare All Versions
Oba 1:1 YBCV (Bibeli Mimọ)
IRAN ti Obadiah. Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi niti Edomu; Awa ti gbọ́ ihìn kan lati ọdọ Oluwa wá, a si ti rán ikọ̀ kan si ãrin awọn keferi, Ẹ dide, ẹ si jẹ ki a dide ogun si i.
Pín
Oba 1 YBCVOba 1:1 YCE (Yoruba Bible)
Ìran tí Ọbadaya rí nìyí, OLUWA Ọlọrun sọ nípa Edomu pé: A ti gbọ́ ìròyìn láti ọ̀dọ̀ OLUWA, ó sì ti rán iranṣẹ rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Ẹ múra, ẹ jẹ́ kí á lọ bá Edomu jagun!”
Pín
Oba 1 YCEOba 1:1 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìran ti Obadiah. Èyí ni OLúWA Olódùmarè wí nípa Edomu. Àwa ti gbọ́ ohùn kan láti ọ̀dọ̀ OLúWA wá, a sì ti rán ikọ̀ kan sí gbogbo kèfèrí láti sọ pé, “Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a dìde ogun sí i.”
Pín
Oba 1 BMYO