ỌBADAYA 1:1
ỌBADAYA 1:1 YCE
Ìran tí Ọbadaya rí nìyí, OLUWA Ọlọrun sọ nípa Edomu pé: A ti gbọ́ ìròyìn láti ọ̀dọ̀ OLUWA, ó sì ti rán iranṣẹ rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Ẹ múra, ẹ jẹ́ kí á lọ bá Edomu jagun!”