Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹk. Jer 4:1

Ẹk. Jer 4:1 Bibeli Mimọ (YBCV)

BAWO ni wura ṣe di baibai! bawo ni wura didara julọ ṣe pada! okuta ibi-mimọ́ li a tuka ni gbogbo ori ita.

Pín
Kà Ẹk. Jer 4

Ẹk. Jer 4:1 Yoruba Bible (YCE)

Wo bí wúrà ti dọ̀tí, tí ojúlówó wúrà sì yipada; tí àwọn òkúta Tẹmpili mímọ́ sì fọ́nká ní gbogbo ìkóríta.

Pín
Kà Ẹk. Jer 4

Ẹk. Jer 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Báwo ni wúrà ṣe sọ ògo dídán rẹ̀ nù, wúrà dídára di àìdán! Òkúta ibi mímọ́ wá túká sí oríta gbogbo òpópó.

Pín
Kà Ẹk. Jer 4
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò