Ẹkun Jeremiah 4:1

Ẹkun Jeremiah 4:1 YCB

Báwo ni wúrà ṣe sọ ògo dídán rẹ̀ nù, wúrà dídára di àìdán! Òkúta ibi mímọ́ wá túká sí oríta gbogbo òpópó.