Job 17:11-12
Job 17:11-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọjọ ti emi ti kọja, iro mi ti fà já, ani iro inu mi. A sọ oru di ọ̀san; nwọn ni, imọlẹ sunmọ ibiti òkunkun de.
Pín
Kà Job 17Ọjọ ti emi ti kọja, iro mi ti fà já, ani iro inu mi. A sọ oru di ọ̀san; nwọn ni, imọlẹ sunmọ ibiti òkunkun de.