Job 17:11-12

Job 17:11-12 YBCV

Ọjọ ti emi ti kọja, iro mi ti fà já, ani iro inu mi. A sọ oru di ọ̀san; nwọn ni, imọlẹ sunmọ ibiti òkunkun de.