Gẹn 34:20 - Compare All Versions

Gẹn 34:20 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ati Hamori ati Ṣekemu ọmọ rẹ̀ wá si ẹnubode ilu wọn, nwọn si bá awọn ara ilu wọn sọ̀rọ wipe

Gẹn 34:20 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Hamori àti Ṣekemu ọmọ rẹ̀ sì wá sí ẹnu ibodè ìlú náà wọn sì bá àwọn ará ìlú náà sọ̀rọ̀.

Gẹn 34:20 YCE (Yoruba Bible)

Hamori ati Ṣekemu, ọmọ rẹ̀ bá lọ sí ẹnubodè ìlú, wọ́n sọ fún àwọn ọkunrin ìlú náà pé