Sekariah 6:12

Sekariah 6:12 BMYO

Sì sọ fún un pé, ‘Báyìí ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé, wo ọkùnrin náà ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹ̀ka; yóò sì yọ ẹ̀ka láti abẹ́ rẹ̀ wá, yóò si kọ́ tẹmpili OLúWA wa.