Sekariah 14:20

Sekariah 14:20 BMYO

Ní ọjọ́ náà ni “mímọ́ sí OLúWA” yóò wà lára ṣaworo ẹṣin: àti àwọn ìkòkò ni ilé OLúWA yóò sì dàbí àwọn ọpọ́n tí ń bẹ níwájú pẹpẹ.