Sekariah 13:8

Sekariah 13:8 YCB

Yóò sì ṣe, ni gbogbo ilẹ̀,” ni OLúWA wí, “a ó gé apá méjì nínú rẹ̀ kúrò yóò sì kú; ṣùgbọ́n apá kẹta yóò kù nínú rẹ̀.