Saamu 128:1-2

Saamu 128:1-2 YCB

Ìbùkún ni fún gbogbo ẹni tí ó bẹ̀rù OLúWA: tí ó sì ń rìn ní ọ̀nà rẹ̀ Nítorí tí ìwọ yóò jẹ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ìbùkún ni fún ọ; yóò sì dára fún ọ