Saamu 104:33

Saamu 104:33 YCB

Ní gbogbo ayé mi ní n ó kọrin sí OLúWA: èmi ó kọrin ìyìn sí OLúWA níwọ̀n ìgbà tí mo wà láààyè.