Saamu 101:1-2

Saamu 101:1-2 YCB

Èmi yóò kọrin ìfẹ́ àti òdodo; sí ọ OLúWA, èmi yóò máa kọrin ìyìn. Èmi yóò máa rin ìrìn mi pẹ̀lú ọgbọ́n láìlẹ́ṣẹ̀, ìgbà wo ni ìwọ yóò wá sí ọ̀dọ̀ mi?