Òwe 25:21-22

Òwe 25:21-22 BMYO

Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ; bí òǹgbẹ bá ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mú. Nípa ṣíṣe báyìí, ìwọ yóò wa ẹ̀yín iná lé e lórí OLúWA yóò sì san ọ ní ẹ̀san rẹ̀ fún ọ.