Numeri 27:18

Numeri 27:18 BMYO

Nígbà náà ní OLúWA sọ fún Mose pé, “Mú Joṣua ọmọ Nuni, ọkùnrin nínú ẹni tí èmi wà, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.