Matiu 7:17-18

Matiu 7:17-18 YCB

Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo igi rere a máa so èso rere ṣùgbọ́n igi búburú a máa so èso búburú. Igi rere kò le so èso búburú, bẹ́ẹ̀ ni igi búburú kò lè so èso rere.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ