Ẹkun Jeremiah 5:19

Ẹkun Jeremiah 5:19 YCB

Ìwọ, OLúWA, jẹ ọba títí láé; ìjọba rẹ dúró láti ìran kan dé ìran mìíràn.