Joṣua 7:19

Joṣua 7:19 YCB

Nígbà náà ní Joṣua sọ fún Akani pé, “Ọmọ mi fi ògo fún OLúWA, Ọlọ́run Israẹli, kí o sì fi ìyìn fún un. Sọ fún mi ohun tí ìwọ ti ṣe, má ṣe fi pamọ́ fún mi.”