Joṣua 23:1

Joṣua 23:1 YCB

Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, nígbà tí OLúWA sì ti fún Israẹli ní ìsinmi kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn tí ó yí wọn ká, nígbà náà Joṣua sì ti di arúgbó.