Jeremiah 5:22

Jeremiah 5:22 BMYO

Kò ha yẹ kí ẹ bẹ̀rù mi?” ni OLúWA wí. “Kò ha yẹ kí ẹ̀yin ó wárìrì níwájú mi bí? Mo fi yanrìn pààlà òkun, èyí tí kò le è rékọjá rẹ̀ láéláé. Ìjì lè jà, kò le è borí rẹ̀; wọ́n le è bú, wọn kò le è rékọjá rẹ̀.