Jeremiah 23:24

Jeremiah 23:24 YCB

Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni lè sápamọ́ sí ibi kọ́lọ́fín kan, kí èmi má ba a rí?” ni OLúWA wí. “Ǹjẹ́ èmi kò ha a kún ọ̀run àti ayé bí?” ni OLúWA wí.