Onidajọ 5:2-3
Onidajọ 5:2-3 BMYO
“Nítorí bí àwọn olórí ti síwájú ní Israẹli, nítorí bi àwọn ènìyàn ti fi tọkàntọkàn wa, ẹ fi ìbùkún fún OLúWA! “Ẹ gbọ́ ẹ̀yin ọba! Ẹ fetí yín sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ-aládé! Èmi yóò kọrin sí OLúWA, èmi yóò kọrin ìyìn sí OLúWA: Ọlọ́run Israẹli.

