Hosea 14:2

Hosea 14:2 YCB

Ẹ gba ọ̀rọ̀ OLúWA gbọ́, kí ẹ sì yípadà sí OLúWA. Ẹ sọ fún un pé: “Darí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá kí o sì fi oore-ọ̀fẹ́ gbà wá, kí àwa kí ó lè fi ètè wa sán an fún ọ