Hosea 10:10

Hosea 10:10 YCB

Nígbà tó bá tẹ́ mi lọ́rùn, èmi yóò fi ìyà jẹ wọ́n; orílẹ̀-èdè yóò kó ra wọn jọ wọ́n ó sì dojúkọ wọn Láti fi wọn sínú ìdè nítorí ìlọ́po ẹ̀ṣẹ̀ wọn.