Esekiẹli 6:10

Esekiẹli 6:10 BMYO

Wọn yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni OLúWA; àti pé kì í ṣe lásán ni mo ń lérí pé èmi yóò mú ìdààmú bá wọn.