Eksodu 9:1

Eksodu 9:1 BMYO

Nígbà náà ni OLúWA sọ fún Mose pé, “Lọ sọ fún Farao, ‘Èyí ni OLúWA Ọlọ́run àwọn Heberu sọ, “Jẹ́ kí àwọn ènìyàn Mi kí ó lọ, kí wọn bá à lè sìn Mí.”