Eksodu 5:2

Eksodu 5:2 BMYO

Farao dáhùn wí pé, “Ta ni OLúWA, tí èmi yóò fi gbọ́rọ̀ sí i lẹ́nu, tí èmi yóò fi jẹ́ kí Israẹli ó lọ? Èmi kò mọ OLúWA, èmi kò sì ní jẹ́ kí Israẹli ó lọ.”