Eksodu 33:17-18

Eksodu 33:17-18 BMYO

OLúWA sì sọ fún Mose pé, “Èmi yóò ṣe ohun gbogbo tí ìwọ ti béèrè, nítorí inú mi dún sí o, Èmi sì mọ̀ ọ́n nípa orúkọ rẹ̀.” Mose sì wí pé, “Nísinsin yìí fi ògo rẹ hàn mí.”