Eksodu 20:7

Eksodu 20:7 BMYO

Ẹ má ṣe ṣi orúkọ OLúWA Ọlọ́run yín lò, torí pé ẹnikẹ́ni tí o bá ṣi orúkọ rẹ̀ lò kì yóò lọ láìjẹ̀bi.