Deuteronomi 4:2

Deuteronomi 4:2 BMYO

Ẹ má ṣe fi kún àwọn ohun tí mo pàṣẹ fún un yín, ẹ kò sì gbọdọ̀ yọ kúrò nínú wọn, ṣùgbọ́n ẹ pa òfin OLúWA Ọlọ́run yín tí mo fún un yín mọ́.