Ìṣe àwọn Aposteli 4:4

Ìṣe àwọn Aposteli 4:4 BMYO

Ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà gbàgbọ́; iye àwọn ọkùnrin náà sì tó ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000).