Ìṣe àwọn Aposteli 2:42

Ìṣe àwọn Aposteli 2:42 BMYO

Wọ́n sì dúró ṣinṣin nínú ẹ̀kọ́ àwọn aposteli, àti ní ìdàpọ̀, ní bíbu àkàrà àti nínú àdúrà.