Ìṣe àwọn Aposteli 1:7

Ìṣe àwọn Aposteli 1:7 BMYO

Ó sì wí fún wọn pé, “Kì í ṣe tiyín ni láti mọ àkókò tàbí ìgbà tí Baba ti yàn nípa àṣẹ òun tìkára rẹ̀.