ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:7

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:7 YCE

Ó dá wọn lóhùn pé, “Kì í ṣe tiyín láti mọ àkókò tabi ìgbà tí Baba ti fi sí ìkáwọ́ ara rẹ̀ nìkan ṣoṣo.